LYRICS: Wale Turner – Awa Noni

 • LYRICS: Wale Turner – Awa Noni

  Verse 1:
  Who be the hardest in the game? Awanoni
  Tani No.1 Bi De Gea? Awanoni
  Talo ma naa yin pa nidi game? Awanoni
  Mgbor Shey Bobrisky Ni G.ay? Sh’awa mo ni?
  Talo ma upgrade level yin?Awanoni
  Talo Tun Le Change Schedule Yin? Awanoni
  Tani Oga Circle Yin? Awanoni
  At last talo ma help yin? Awanoni
  Awon wo ni baba 4 the girls? Awanoni
  Ni party yin awon wo ni guest? Awanoni
  Awon wo lo blend yin te fi bem? Awanoni
  Talowa pelu girlfriend yin lori bed? Sh’awa mo ni?
  Talo ko daddy yin bo shey n rap? Awanoni
  Ta lo ma ri picture yin ta double tap? Awanoni
  Talo ma fowo gba babe yin? Awanoni
  Talo ra oti to wa n table yin? Awanoni

  Verse 2:
  Awon wo lo n Pa gbogbo beat? Awanoni
  Tani chairman gbogbo bii?Awanoni
  Awon wo ni o like osho free? Awanoni
  Talo ma form to ba ri Mikel Obi? Sh’awa mo ni?
  Awon wo lo wa lati gutter? Awanoni
  Awon wo lo fe ajeB.utter? Awanoni
  Awon wo lo n beebe lati ri? Awanoni
  Won de so pe oju won ti ri? Sh’awa mo ni?
  Awon wo ni booda oni dada? Awanoni
  LastLast Awon Wo Lo N Shey Dada? Awanoni
  Awon Wo Ni Students Like? Awanoni
  U dey among the people wey dem like? Sh’awa mo ni?
  Awon wo lomo Ketu? Awanoni
  Rap Talo N Ma gbo to ma ni Jesu? Awanoni
  Awon wo lo n burst speakers yin? Awanoni
  Ki de loruko hit track yii? AWANONI

  SEE ALSO  Lyrics: Olamide Ft. Phyno – On A Must Buzz

  Verse 3:
  Awon wo lo n top gbogbo chat? Awanoni
  Awon wo lo n l’eko d’abuja?Awanoni
  Awon wo lo ti pe tan ti ja? Awanoni
  Ati we eh tun sope shotiya? Sh’awa mo ni?
  Awon wo lo n burst brain yin? Awanoni
  Awon wo lo le burst game yin? Awanoni
  Awon wo ladajo ninu court? Awanoni
  Abi talo meran ninu pot? Sh’awa mo ni?
  Awon wo leyan Shina Peller? Awanoni
  Awon wo leyan EMoney? Awanoni
  Awon wo leyan EbayCarder? Awanoni
  Awon wo leyan Juwonlo? Awanoni
  Awon wo leyan Akuebe? Awanoni
  Awon wo leyan Headboy Ketu? Awanoni
  Awon WO leyan Aliu Champion? Awanoni
  Awon wo leyan Jimmy Jatt? Awanoni
  Awon wo leyan V.J Adams? Awanoni
  Awon wo leyan Mowey? Awanoni
  Awon wo leyan Awazi? Awanoni
  DO2DTUN ? nko? Awanoni
  Awon wo leyan Kemi Smallz? Awanoni
  Awon wo leyan Gbemi? Awanoni
  Awon wo leyan Olisah? Awanoni
  Awon wo leyan ToolzO? Awanoni
  Awon wo leyan CaptainDemu? Awanoni
  Awon wo leyan HoneyPot? Awanoni
  Awon wo leyan Shopsidoo? Awanoni
  Awon wo leyan Lapizee? Awanoni

 • 0 Comments

  Leave a Reply